Académique Documents
Professionnel Documents
Culture Documents
http://ask-dl.fas.harvard.edu/content/10-eji-ogbe
Eji Ogbe 1
Lo wa nl yii o.
Eji Ogbe lo wa nl yii.
Ifa n s fun eleyi wipe ki eleyi rub nb ko ma ba sanw ire ti n wa.
Eleyi... o n wa ire.
Ko kooo ko rub nb.
Gbogbo ire ti n wa, Ifa ni w r, o to, ti o ba ti le rub.
So ti o ba ti rub, o maa...
Ko le ri o.
O maa lose .
Mas se ele (a) fizer sacrifcio, ele vai ganhar isso.
Ifa ni ko rub nb.
Ko ma ba sanw ire ti n wa o, lodu Eji Ogbe o.
Nibi Ifa naa gba ti s b ni o. Ifa na s pe:
tt, r rr, tt laa jp.
tt nla j mumi.
Ohun tori tori, ohun tore tore nlaa fba Makin nile Iranje, ko ba le fi ohun to ri to re ta
ni lre a dia fun Ogotr yi ti n gbgun l hinwran.
Ogotr lork a n poko.
hinwran lork a n pobo.
w r oko ii Jagun ilobo ko sanw .
Ifa wipe eleyi ko rub nb, ko ni sanw ire ti n wa nb.
Gbogbo ohun ti n wa yio to lw, to ba ti rub nb.
Ko ba etutu fun awn aiye plu rrn.
Lw r o fi t nkan ti n wa loju Eji Ogbe ni.
Eji Ogbe 1
Este j Ogb.
Ifa est dizendo a esta pessoa deve fazer um sacrifcio para que ele (a) no entra de
mos vazias e no perca a nica coisa boa que ele (a) est procurando.
Esta pessoa est buscando uma bno (fortuna).
Ele (a) deve fazer um sacrifcio.
Todas as bnos esto vindo para ele / ela, e Ifa diz que ele (a) vai encontr-lo / se ele
(a) oferecer sacrifcio.
Se ele (a) no oferecer um sacrifcio, ele (a) vai ...
Ele no poder alcan-lo.
Ele vai perd-la.
Mas se ele (a) faz um sacrifcio, ele (a) vai receber.
Ifa diz, ele (a) deve oferecer um sacrifcio para que ele (a) no pode acabar mal
sucedido, esta mensagem Eji Ogbe.
Esta a maneira Ifa nos ensina a falar esta mensagem.
Ele diz:
tt, r rr, Ototo (O que real real [verdadeiro], o que no real no real),
Inteiro como comemos amendoim.
Inteiro como ns comemos imumu (semente preta comestvel).
Em Iranje, eles avaliam valor do rei atravs do seu desempenho.
Se voc elogia o rei com seus atos de bravura, ele vai lhe dar um presente.
Isso revela por que Ogotr fez guerra contra Ehinwran.
Ogotr o que chamamos de pnis, e hinwran o que chamamos vagina.
uma abominao para os deuses ver o pnis lutar uma guerra com a vagina e perder.
If diz que esta pessoa deve oferecer um sacrifcio, para que ele (a) possa alcanar a
bno que ele (a) est procurando.
Tudo o que ele (a) est buscando, ele (a) certamente ir obt-lo se ele (a) faz um
sacrifcio. Ele (a) deve fazer oferendas para os seres espiritualmente poderosos.
Essa pessoa vai ser capaz de obter o que seu corao deseja muito facilmente.
Isto o que Eji Ogbe nos diz.
Eji Ogbe 2
Loju Eji Ogbe naa ew, ti Ifa ba gbe e, Ifa pe eleyi ni obnrin pupa nile, o niyawo pupa
nile, ko rub ntor , kk o ma...
Kk o ma baa paa m lw ka ka, kmi r o le ba gun.
Ifa ni eleyi ni obinrin pupa nile, ko rub ntor , kk o maa paa m lw.
Loju Eji Ogbe naa tifa ba gbe e.
Nibi ti Ifa naa ti s b re o, to pe obinrin pupa kan nu ninu ile yii, ko rub nb kk o
maa paa m lw. Ifa naa s pe:
Sinima-Sinima, a dia fun obinrin pupa rororo eyi ti e iyawo runmila nijti l re na
iyaku lj jgbmkn.
A ni Sinima re, o n l j jgbmkn.
Ngbo doja jgbmkn, o ba iya kan pade nb, gbn iyaku ni ni to ba pade, but ko
wa m.
Nigba Ija de saarin wn to ba AH!
To na gidi!
Awn eniyan ba pe, ah iya iku l na.
Heh?!
Iru iya wo ni!
Kni j iyaku, ko m tm iku.
O na iya de bi wipe, mi si f b.
Niyawo runmila, nigba o wa dele, lo wa dele ni s fun k r, Ah! O ni, Baba!
O ni oun baya kan pade ni j jgbmkn loni.
O ni lo ba f roun fin, o lo naaaa yiyi!
O ni, iru iya wo, runmila n iru iya wo a ni?
O na to ah, o ni iyaaku na n pe e. Ah! runmila ni, gbg! Iyaku lo na! Ah! Iru kini w
obinrin yii wa e yi ooooo, abi o m n to n wi ni? Ah o lo n na p ni . O lo n m n to n
wi. Iyaku na si, o ni iyaku ni.
runmila ba sare gbefa kal, lo df. Ifa ba s fun runmila pe, Ko tete rub o!
Kk ma paa m lw o. Ko si tete kun obinrin, gbogbo obinrin to pupa nile .
Ko kun wn ni bj ko gbogbo wn o dudu o.
Tori to ba rii obinrin pupa nb, iku o mu gbogbo won l o.
Loju s runmila tii..., gbogbo ohun ti wn ni krnml ru lb, o ti ru u.
O gb riru, o ru. O gb titu, o tu. O gb harahara loju pn, o ha.
Gbogbo ohun a ni o e, o ti e.
O ti y o?
O ti baa jawe Ifa... Ibj.
O ti wa bj l, a n pe kini kan ni bj.
Ta ba ti fi kun eniyan by, yio. Eniyan pupa yio dudu ni.
Ka runmila ti wa bj l ti wa oko Ifa l.
Wn ti etutu, wn ti kun gbogbo obinrin ti o pupa nile runmila ni bj.
O par . To ba ni...
Nigbo doj kej by ni iku ba de.
Iku, o si ni kondo kondo ku kii gun ju by l.
Nigba o e de iwj ita runmila by, iku kan roll kondo soke by nigba loju by.
Ni o ba joko nil. O ni, w runmila!
runmila lo n j.
O ni, iyawo r na iya lj jgbmkn lanaa.
runmila ni, kii e iyawo oun! Ah!
O ni, kii e iyawo r bo?
runmila ni, kii e iyawo oun. Kii e iyawo r?
runmila ni, kii e iyawo oun. Kii e w lo ni obinrin to pupa roro kan by?
runmila ni oun o lbnrin pupa nile. Oun o lbnrin pupa nile?
O ni bni. Iku ni o da, ko gbogbo obinrin inu ile r jade nigba naa.
Koun yw.
Bi runmila ti ko gbogbo awn obinrin to wa ninu ile jade l pata pata!
runmila si niyawo pp.
Niku wa la aarin wn lo ga rarara.
Ni wa obinrin pupa nb, ko ri i.
O la l, la b, rin lrin, brin lrin, b [O laa l, o laa b, o rin in l, o rin in b], ko ri
i. Gbg!
Niku bu kn lo ni iya lo j oun toto by.
e kii e iyawo, kii e iyawo ni.
O na... o ni kii e iyawo oun, oloun o lbnrin pupa nile e.
Ngba ti o ri obinrin pupa nb, biku e sunkun l nuun.
Lrnml ba n yin awn awo r, lwn awo r ba n yinfa.
runmila ni b gg lawo wi o, b gg nw toun s.
O ni:
Sinima Sinima lo difa fun obinrin pupa rororo eyi ti e iyawo runmila nijo ti o n l re
na iyaku lj jgbmkn.
O n ek sonibuje ma, Sinima, Sinima
Arn sonibuje ma, Sinima, Sinima
Ofo sonibuje ma, Sinima, Sinima
Aseeri sonibuje ma, Sinima, Sinima
Afaato sonibuje ma, Sinima, Sinima
Idamu sonibuje ma, Sinima, Sinima
Ba un ni runmila e br si n yinfa nuun. Ifa n yin Eleduma...
Eji Ogbe 2
Neste Eji Ogbe, Se revelado pelo If, esta pessoa tem uma mulher de pele clara na
casa como uma esposa.
Ele deve oferecer um sacrifcio imediato para que a morte no mat-la sob sua
superviso, e ela pode ter uma vida longa.
If diz que esta pessoa tem uma mulher de pele clara em casa.
Ele deve oferecer um sacrifcio para que a morte no lev-la embora.
Isto o que Eji Ogbe nos diz, esta a mensagem que If transmite.
Aqui, isso o que Ifa diz, h uma mulher de pele clara na casa dessa pessoa, e ele tem
que fazer um sacrifcio para evitar a morte de lev-la embora.
Ifa diz:
Sinima-Sinima vai para dizer sobre uma mulher de pele clara, o que foi / a esposa de
Orunmila, no dia em que ela bateu na me da Morte no mercado jgbmkn.
Diz-se que Sinima estava indo ao mercado jgbmkn.
Quando chegou jgbmkn, ela conheceu uma velha l,
Mas no sabia que ela era a me da morte.
Quando uma luta surgiu entre eles, Sinima a venceu intensamente.
Todo mundo disse:
Ah! Essa a me da morte que voc espancado.
Ela respondeu:
A me?
O que quer dizer a me da morte?
Isso no significa nada para mim.
Ela bateu na anci at ela quse morrer.
Quando a esposa de rnml chegou em casa, ela disse ao marido:
Ah! Baba, eu bati em uma mulher de idade hoje no mercado jgbmkn.
Ela disse que queria me envergonhar, e eu a bati nela severamente.
Perguntou rnml,
Quem era a velha senhora?
Eles disseram que ela era a me da morte, respondeu Sinima.
Ah!
rnml disse.
Voc bateu na me da morte?
Sim!
Voc mulher, o que voc fez?
Voc sabe o que voc est dizendo?
Ela respondeu, eu j respondi a voc, claro que eu sei o que estou dizendo.
Ele perguntou de novo,
A me da morte?