Vous êtes sur la page 1sur 2

EYONU 1.

Epo die 2. Iyo die 3. Omi die ao ro po, ao te ifa eji ogbe si pelu ofo yii. Omo
pon loruko ti a npe epo 3x Omo dun loruko ti a npe iyo 3x Awaye ma te
loruko ti a npe omi 3x Omo pon loruko ti a npe Epo, ti Lagbaja ba je epo loni
ki o ma yonu si emi Lagbaja 3x Omo dun loruko ti a npe iyo, ti lagbaja ba je
Iyo loni ki o ma yonu si emi Lagbaja 3x Awaye ma tee loruko ti a npe omi, ti
Lagbaja ba mu omi loni ti o ba ti ri emi lagbaja ki o ma yo mo emi Lagbaja
loni yi o ao la epo yen ao fi iyoku paa oju
OGUN EYONU TI A MALO LO SI ODE TAFI GBA IYIN NI BE
ao fi epo pupa te ejiogbe si atelewo alafia,ao tun fi omi na te pelu iyo
isebe,ao wa pe ohun yi si ao wa la,ao fi owo iyoku sa ori,kama lo sode na ao
gba iyin nibe, ohun re:
amo roro loruko ti won pe iwo epo,
amayegun loruko ti won pe iwo omi,
amuludun loruko ti won pe iwo iyo,
omi kiti laye o,
ejiogbe kiti lawujo ifa,
ki emi lagbaja omo lagbaja gba iyin nibi gbogbo loni o.
ejiogbe
!!
!!
!!
!!
ogun yi dara gan ni o asegbayin la o ma se o ni ojojumo aye wa ao ni te lase
edunmare

Onfa iferan
Ao bu iyo, epo, omi,is atelewo ao pe ofore sii bayii
Aponroro ni oruko tanpe epo
Ajifunfun yinyin loruko ti anpe iyo
Awolu mate ni oruko tanpe omi
Emi tidi meteta loni ti _ omo_
bati jeun epo emi ni koma ranti toba
jeun iyo emi ni koma ranti toba
mumi emi ni koma ranti lati onilo ao wa la loba tan

IF YOU WANT TO GO AND COLLECT A CONTRACT AND YOU KNOW THE


NAME OF THE PERSON IN-CHARGE
iyo ati omi, ao da gbogbo re sinu "CUP".
Ao waa te odu yi sori IYO(Salt):EJIOGBE

!!
!!
!!
!!
Omo-pon loruko aape Omi.
Bi LAGBAJA bamu omi loni, Bio bati rimi, nise ko maa jo momi, ko maa yo momi.
Omo-dun loruko aape iyo,
bi LAGBAJA baje iyo loni,
Bio bati rimi, seni komaa jo momi,
komaa yo momi.
Awaye-mate loruko aape Omi.
Bi LAGBAJA bamu omi loni, bio ba tirimi,
nise ni ko maa jo momi, ko maa yo momi.
Arijo ariyo niti omo tuntun oojo.
<AO WAA DA IYO YI SINU OMI ATI EPO NAA, AO WAA MUU>.
IF YOU DON'T GET THE CONTRACT AFTER USING IT, PLEASE! "UNLIKE"
THIS PAGE.

Vous aimerez peut-être aussi