Vous êtes sur la page 1sur 3

IWURE; ORI

BI ORI BA FOJU KANNA


YIYO NII YO
BI EPO BA FOYU KANNA
YIYO NII YO
BI ADI BA FOYU KANNA
YIYO NI YO
IBI TI MO N LO LONII
KOMODE YONU SI MI
AGBE NI GBERE PADE OLOKUN
ALUKO NI GBERE PADE OLOSA
ODIDERE NI GBERE PADE ONIWOO
ONIWOO OMO ODO OBA
OMO ODO OBA ATOLUMERE
ELA IWORI
WA GBERE PADE MI LONII.

KILO NGBE NI TO-TO ORI EJE N GBO


KO SI O, ORI GBE MI O
ORI PELE O, ATETE NIRAN
K'ORI SUN WA SIWAJU
ORI LALA 'YANMON ENI, AKUNLEYAN
BI MO JI LOWURO, MA YA GBARI MI MU
LOJO DIDUN NI, TABI KOJO KIKAN
ORI NI ALASIN WAYE ENI
ORI MI MA PADA LEYIN MI
IRAWO KII PADA LEYIN OSU
ORI MI MA PADA LEYIN MI. ASE

ORI LO FI AGBE JOBA NILU IKARO


ORI LO FI ALUKO JOBA NILU IKOSUN
ORI LO FI LEKELEKE EYE ABIYE FUNFUN
JOBA NILU IKEFUN
ORI MI A BO SUN
PERE KI A, KI O JI
LA ONA OLA KO MI
KI O SE TEMI LASE LA
MA JE N SOWO ASE DANU. ASE

KI NLE 'KE ODI.


KIEMAA GBE'MI N'IJA KIEMAA GBE MI LEKE
ISORO LOJO GBOGBO NI GBOGBO OJO AYE MI.
KIEMAA GBE 'RE.
BI'KU BA SUNMO ITOSI KI E BAMI YE OJO IKU.
ODUN TIATIBI MI SINU AYE KI E BAMI YE OJO IKU FUN ARA MI ATI AWON OMO MI TI MO
BI. KIAMAKU NI KEKERE, KIAMAKU IKU INA, KIAMAKU IKU ORO, KIAMAKU IKE EJO,
KIAMAKU SINU OMI.
KI E MAF'FOJU RE WO MI, KI AWON OMO ARAYE LEE MAA FI OJU RERE WO MI.
KI E MA JEKI NSAISAN KI NSEGUN ODI KI NREHIN OTA. GINA HUANG, BERRYL HUANG
ETC.
KI E MA AWON OMO ARAYE GBURO, MI PE MO L'OWO LOWO PE MO NIYI, PE MO N'OLA,
PE MO BIMO RERE ATI BEEBEE.
KI E SI'NA AJE FUN ME, KI AWON OMO ARAYE WA MAA BAMI, RA OJA TI MO BA NIITA
WARAWARA, IPEKU ORUN E PEHINDA LODO MI.
KI E DA MI NI ABIYAMO TIYOO BIMO RERE TI WON, YOO GB'EHIN SI SINU AYE ATE
BEEBEE.
KI E KA IBI KURO LONA FUN MI LODE AYE.
KI E BAMI KA'WO IKU, ARUN EJO OFO OFO EFUN EDI APETA OSO.
KI O R'OMO GBE SIRE, KI E JEKI ORUKO MI HAN SI RERE, KI IPA MI LAYE MA PARUN.
KI E JEKI NGBOKI NTO KI NPA EWU S'EHIN.
ASE, ASE, ASE, 'SE O.

AWURE.
EFUN ADO, OSUN, IMI OJO PUPA, AO LOPO MO OSE DUDU,
TABI LUX, AA MAA FI WE LARARO.

AWURE OWO.
OGA AYE, TAGIRI, IGBE EWURE TO BIMO RE, IGBE AGUNTAN TO BIMU RI . OSE DUDU 300, AO
GUN PO, AO MA FIWE LARARO: (GBOLOHUN RE) BORO BORO LEWURE SU MI RE, BORO
BORO LAGUNTAN SU MI RE, OJOJUMO NI TAGIRI NKA OWO TIE, ABA TI ALAGEMO BADA NI
ORISA OKE NGBA, MO DABA KI WON MA MU NLA NLA WA FUN MI LONI.

AWURE OWO.
EGBO ILA IROKO, EGBO IPON, AKA IDI ESU, OSE DUDU, AO GUN GBOGBO RE PO, AO MA FI
WE LARARO., GBOLOHUN: IPON LONI KAN PINRE TEMI FUN MI LONI, IROKO LONI KAN RU
IRE TEMI FUNMI LONI, OJU KII MO KAN MO TA ESU LORE, KI TOMODETAGBA, WA MA FI OWO
NLA NLA TA EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA LORE LONI.

AWURE AWORO OWO.


OGEDE WEWE PUPA, EWE ESINSIN FUN FUN, EWE SAWEREPEPE, EWE OYO, EWE REKUREKU,
AO GUN PAPO., AO FI IYO LO PAPO, AO RO SINU ADO IJAMO, AO SO SI ENU ONA ILE.

IMULE OWO
EGBO OROGBO, ERU, AKO OKUTA, OMIDUN OGI, AO FI IYO TELE INU ORU, AO KO OKUTA
AKO SI, AO KO EGBO OROGBO LE, AO DA OMI OGI LELORI.
IMULE OWO
ERAN ETU, ESO OGIRISAKO, ATA IJOSI IYO, EPO, AO SE LOBE.

AWURE OWO.
OPOLO NLA, AO RO EPO PUPA SI LENU, AO WA #100 TUNTUN, AO KO #10,000 SI WAJU #100
YEN, EYIN RE AO KO I NEED #10,000, AO WA JO PELU ODIDI ATARE KAN. AO WAIF FO EKO
MU, AO MU SCHINAP LE.
AWURE OWO GBIGBA.
AFARA OYIN, IPE IRE, ODIDI ATARE KAN,
AO JO PO,
AO RO SINU IGO,
AO MA BU SINU IPARA DIEDIE.
-------------
AGBE NI I GBE'RE K'OLOKUN
ALUKO NI I GBE'RE K'OLOSA
ODIDERE-MOBA-ODO OMO AGBEGBAAJE-KA NI
NAA NI I GBE'RE K'OLUWOO;
ELA-LWORI, .GBERE PADE LONA DANDAN
OLOJO-ESINMINRIN-KUNTELU-TELU
JE K' AJE WA KU SILE BAYII, IBIOKABASI,
IGBA ERANKO NI BA NIBE TI I JE;
IFA ERE KII-JE K' EBI KO
OJU KAN TESA BA'JOKOO SI
LAA GBE' RE TIREE WA BA
HE NI ATASO N JOKO T'OKEREKERE I WO TO
LLETATAPO IJOKODE'DI:
AJIGBORE NI T'AATAN;
OJUMO KII MO K'AATAN MO GBORE
OLOJO-ONI TATEMI LORE
GBOGBO OMI NI I FORI FOLOKUN;
L GBOGBO ABATA NI I FORI FOLODO, ''
ISE GBOGBO AGBARA L BA SE
OLODO NI I FI SIN;
OSIN LO NI KI WON WA SIN
ASO ALAPO LOGA I GBA;
TI GBO TI'JU NI J GBONWU EEGUN
OMODE ILU, AGBA ILU, E WAA FIRE GBOGBO SIN MI O
IRE GBOGBO LAGBARA FI SIN OLODO.
IRE GBOGBO

OFO AWURE
OFO AWURE
OFO OWO
OFO BI INU BA TI RUN
ENIYAN
OFO TA A FI N TI OJO