Académique Documents
Professionnel Documents
Culture Documents
ÒÒ risa para que la fiesta seraó celebrada es ese rey de la córóna que estaó tómandó su ó
su banñ ó espiritual. ÒÒ ruó nmììlaì en ÒÒ tuó ruó póì n-ÒÒ fuó n dijó Edu a unó de sus sacerdótes para
siempre lavar sus manós y pies antes de realizar cualquier ritual.
Òòrùn jí ní kùtùkùtù
Ko yèrìyèrì
A dífá fún won ní Kàáà à-jí-jáwé
Ewé awó sà
Kà sàì jé rere o
Ewé awó sà.
Orin:
Ewé awó sà món jé o
Gbogbo ìsèlè
Àìsà máa jé o
Gbogbo ìsèlè.
Lílé: Gbobì je o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbobì je o
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Gbobì je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Gbata je o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbata je o
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Gbata je o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Gbotí mun o
Ègbè: Igba ewé èlùjù
Gbotí mun o
Igba ewé èlùjù
Lílé: Ò bá gbotí
Kí nní ire gbogbo nígba nígba
Ègbè: Gbotí mu o
Igba ewé èlùjù
Gbotí mun o
Igba ewé èlùjù
- Ògúndá Òbàrà.
-Òfún méjì.
Orin:
Òdúndún ma ní tèwèrù 2x
Bóbá dàmòdun
Ma lé tèwèrù
Òdúndún ma ní tèwèrù
Tètè-àdáyébá, el viridis del Amaranto.
Teì teì pertenece a la familia de Amaranthaceae. Lós miembrós de esta familia són
anuales ó planta perenne cón lós tallós derechós. Ellós raramente són trepadóres ó
arbustós. Ellós tienen en situacióó n ópuesta ó el arregló de las hójas alternadó. Muchó
lós miembrós familiares sóbre tódó, el geó neró del Amarantó es las verduras
cómestibles impórtantes. El viridis del amarantó tiene muchas própiedades
medicinales.
Bí àgbàdo bá yo ìrùkèrè
Kò jé fi lé omo elòmíràn lówó
A pin Téélé-téélé kárí omo re
A dífá fún esè kan soso Ogbè
Tí won ní kò ní telè yí pé
Ebo ni wón ní kóse
Òun sì gbébo níbè ó rúbo
Njé tani onílè tóni
Tètè kò má telè
Tètè tèé rere
Ìwo ni onílè
Tètè tèé rere.
Ogbè-Atè
Orin:
Ta lonílè tóni
Tètè kò má te
Tètè tèé rere
Se bíwo lonílè
Tètè tèé rere.
Orin:
Odán dolóde 2x
Kèrèkèrè
Odán dolóde.
Ayé kanpá
Èlè ló kù
Ò dífá fún Aragbandù
Tí ó nlo jákùn ikú
Njé mo jákú mo járùn
Mo já sasara.
Orin:
Líle: Mò jákú o
Mo járùn o
Ègbè: Sasara
Mò jákú o
Mo járùn o
Sasara
Líle: Mò jéjó o
Mo jóràn o
Ègbè: Sasara
Mò jéjó o
Mo jóràn o
Sasara
Èlà yìn-ìn
Babaláwo isin
Lóki Ifa fún isin
Isin nbe lárìn òtá
Ebo ni w’on ní kóse
Ó gbébo níbè ó rúbo
È bá jáwé isin
È bá wagbò isin
Oró tí e dá isin
Isin kò sà ì là.
Orin:
Isin kò sàìlà 2x
Oró tí e dá sin o
Isin kò sà ì là
Orin
Òwú dé awo ògòdò o 2x
Sebí terú, tomo lòwú là o.
Yími ébè
Kí nyí e sí poro
Ó dífá fún gòdògbó
Tí rayé ìlaìnikú
Ebo wón ní kóse
Òun sì gbébo níbè ó rúbo
Kèèpé o, kèèjìnà
E wá bá ni láìkú kangidi
Àìkú kangidi làábáni lésè oba Òrìsà
Orin :
Kò ní bá won
Kúkú òwowòó
Gòdògbó o
Kò ní bá won.
Pèrègún, el smithii de Draceana,
La planta pertenece a la familia de Agavaceae, el smithii de Draceana, es un miembró
impórtante de esta familia. Nórmalmente se planta pór demarcar lós lìómites en
Yórubaland y tambieó n encóntróó muchó en las urnas y ranuras. Tiene las hójas largas
apróximadamente 20 metrós largó. Las hójas són a menudó largas, espesas y
córiaó ceas.
Ogbè sáàsáà
A dífá fún pèrègún lègèlègè
Tí omo aráyé yóò máa rò pa Ebo wón ní kóse
Òun sì gbébo níbè ó rúbo
Njé pèrègún kò loso èsín mó
Bí odún bá dun
Pèrègún a dá aso tuntun
Pápásan Èèsún
Rinrin Sàájé Portulaca oleraceae
Ògègé Gbégi Lóbòntujè
Ètìpón-olá
Orin:
Lílé: Érún Érún Lílé: Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún. Obaládé mà nwè
Lílé: Érún lájé Ègbè: Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún. Lílé: Èjìogbè, Oba n’Ifá
Lílé: Érún níre gbogbo Ègbè: Sùsù o
Ègbè: Erun Èrún. Obaládé mà nwè
Sùsù o .