Vous êtes sur la page 1sur 21

GBOGBO AIYE GBE

JESU GA

Gbogbo aiye gbe


Jesu ga
Angeli ewole fun /
2ce
E mu ade oba re wa
Se loba, Se loba
awon oba

Eyin iru omo Israel


Ti a ti rapada/2ce
Eki enito gba yin la
Se loba, Se loba
awon oba

Ki gbogbo
orile ede
Ni gbogbo
agbaiye/2ce
Ki nwon ki
Kabiyesile
Se loba,
se loba awon oba.

A ba le pel
awon torun
Lati ma juba re
Ka ba le jojumo
korin Se loba, se
loba awon oba.

OKAN MI YIN OBA


ORUN

Okan mi yin oba orun


Mu ore wa sodo re
Wo tawosan, tadariji
Tala ba yin bire
Yin Oluwa,
Yin Oba Ainipekun

Yin fun aanu to ti fi


han
Fawon Baba nnu
ponju
Yin I, okan na ni titi
O loro lati binu
Yin Oluwa
Ologo nnu otito

Bi baba ni o ntoju
wa
O si mo ailera wa
Jeje lo gbe wa lapa
re
O gba wa lowo ota
Yin Oluwa
Aanu re yin aye ka

Angel ejumo bawa


bo
Enyin ri loju koju
Orun osupa e wole
Ati gbogbo agbaiye
E bawayin
Olorun olotito

MA KOJA MI OLUGBALA

Ma koja mi Olugbala
Gbo adura mi
Gbati wo ba npe
elomiran
Mase koja mi

Chorus.
Jesu/2ce gbo adura
mi
Gbati wo ba npe
elomiran
Mase koja mi

Nite aanu ke
kemi ri
Itura didun
Teduntedun ni mo
wole
Jo ran mi lowo

Chorus.
Jesu/2ce gbo adura
mi
Gbati wo ba npe
elomiran
Mase koja mi

Nigbele Itoye re
Lemo woju re
Wo banuje okan
mi san
Fife re gbami

Chorus.
Jesu/2ce gbo adura
mi
Gbati wo ba npe
elomiran
Mase koja mi

Wo orisun
itunu mi
Ju ye fun mi lo
Tani mo ni laiye,
lorun
Bikose iwo

Vous aimerez peut-être aussi